Home LÁGBO ÀRÍYÁ Funke Akindele ati Eniola Badmus ni ko sija laarin awon
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 23, 2017

Funke Akindele ati Eniola Badmus ni ko sija laarin awon

Ni odun die seyin, ore timotimo ni Funke Akindele ati Eniola Badmus je. Opo eniyan gba pe korikosun ni won. Paapaa nigba ti Funke sese se JENIFA, ipa ti Eniola ko nibe kii se keremi.
Sugbon leyin igba die, ko jo pe aarin won dan moran mo. Won ko jo rin po, bee ni won ko jo sise po dabi alara. Eyi fa a ti awon amoye se ro pe ofon-on I to si gbegiri laarin won; ko onikaluku ko eko re lowo.
Amo bayii, awon mejeeji ti ni ko sija. Ko sita laarin awon. Lati fi idi eyi mule, won sese gbe awon foto kan ti won sese joy a ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…