Home iroyin ERÍN WÓ! Ikú pa Adébáyọ̀ Fálétí
iroyin - July 23, 2017

ERÍN WÓ! Ikú pa Adébáyọ̀ Fálétí

Ogbontarigi osere, akowe ati agbasaga, Alagba Adebayo Faleti, ti di oloogbe.
Iroyin iku Faleti sese n jade ni felifeli ni, ti o si mu edun okan ba opo eniyan.
Lati nnkan bii odun mefa seyin ni aare ti mu baba naa mole.
Koda, ni odun 2014, awon alaheso ko so pe Faleti ti ku.
Sugbon olojo ko tii de nigba naa.
Osise iroyin ni Faleti tele, ko to dip e o n se ere tiata ati fiimu.
Opo eniyan ko le gbagbe ipa nla to ko ninu awon fiimu bii Basorun Gaa, Saworoide ati Thunderbolt.
Ki Olorun te baba naa si afefe rere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…