Home LÁGBO ÀRÍYÁ Èmi ò kówó jẹ ò – 2 Face
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 23, 2017

Èmi ò kówó jẹ ò – 2 Face

Gbaju-gbaja okorin ti gbogbo aye mo si 2 face Idibia ni awon kan ti n gbee poori enu pe o kowo ti won dajo nibi ikowo-jo fun awon ti idaamu kan tabi omiran ko je ki won ni ile lori ni orileede won (Internally Displaced Persons IDPs) je.

Akole ikowojo naa ni “Eargasm”ni eyi to ti bere lati odun 2012. Odoodun si ni ikowojo naa maa n waye ni ara otun pelu orin. 2 Faces ni oun ko le maa sepe fun ara oun nitori pe, isoro lo de ba awon ti awon n se konsaati fun ki won le rowo mu lo enu. O ni ko tun wa ni dara ki iru owo bee poora, Idibia tun fi kun un pe gbogbo eni to ba n ja ile onille bo tire mole n sepe fun ara re ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…