Èmi kò ní Àrùn Cancer o –Halimat Abubakar
Ilumooka osere Nollywood, Halimat Abubakar lo ti ke gbajare saraye pe oun ko ni arun jefun-jedo (Cancer) gege bi awon ota oun se n gbee kiri. O ni awon kan tile baa bebi wi pe won tun fi n gbowo lowo awon eniyan kiri.
Halimat ni loooto ni o re oun ti oun si ti sise abe lori arun Iju (Fibroid) ni orileede India ni nnkan bii osu meji seyin, ara si ti ya. O ni oun fi asiko yii dupe lowo awon eniyan ti Olorun fi ke oun. O ni pelu awon eniyan naa, ko le si isoro to maa mu ki oun toro owo kiri ilu fun iwosan.
O ni oun dupe lowo awon ti won pe oun lori aago ati awon to n fi adura ranse. O ni sugbon to ba ti n la dawo-dawo lo, ki awon ara ilu soji kia, ko si ohun to joo.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…