ERÉ ÌDÁRAYÁ - July 23, 2017

Tori Morata, Conte le Costa danu

Fagidi-jaye agbaboolu Chelsea, Diegp Costa, ni won ti le danu bayii o.

Adari Chelsea, Antonio Coasta ti so pe ‘bye bye’ fun Costa, tori Olorun ti bota buredi re lona miiran.

Eyi sele nipa didarapo ti Morata fe darapo mo Chelsea lati Real Madrid.

Ara ohun to dun Conte ju nip e eemeta ni Costa dun mahuru mahuru mo o lodun to lo, nigba to so pe oun fe fi Chelsea sile.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…