Tinubu dunnu lori bi awon eniyan se jade dibo
Ati yanju gbogbo ikunsinu – Tinubu
Olori Egbe APC, Asiwaju Bola Tinubu, ti fi idunnu han lori bi awon eniyan se jade dibo ijoba ibile ni Ipinle Eko lonii.
Tinubu ni awon eniyan gbo ipe Gomina Akinwunmi Ambode, won si tu yaaya jade.
Lori awuyewuye to wa ninu egbe naa nigba ti ibo sun mo etile, Tinubu ni ko si wahala rara.
O ni gbogbo ariyanjiyan to saaba maa n waye ti iru eto bee ba n waye ni awon ti yanju.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…