Home ÀṢÀ ÀTI ÌṢE Orí Ọ̀kẹ́rẹ́
ÀṢÀ ÀTI ÌṢE - July 22, 2017

Orí Ọ̀kẹ́rẹ́

Yooba bo won ni ori okere kooko lawo, baawi fomo eni a gbo.Ko si oro yooba ti o see ko danu, idi niyi ti yooba fi n lo owe yii, lati se ikilo fun eni yoowu ti o ba n se ohunkohun ti o seese ki o mewu dani fun-un tabi ebii re.Okere je irufe eranko kan ti o ni anfaani to po gan-an,ti o si feran lati maa je lopo igba nibi ti o lewu, lara igi,tabi loke e ope ,irun si yii ni gbogbo ara,debi iru re.Bi o tile je pe, kii se eranko kan ti o tobi,sibe,oju kii rina aso ko maa pa a ni olode maa n fi se.Eranko yii feran-an ki o maa (ke,tabi  dun)lati sofofo tabi tu asiri pe eranko mi-in tii o lagbara wa nitosi.Okere je eya eranko ti o maa n gbabode ,wojuure omo eniyan ,lati safihan eranko egbe e re mi-in. Nibi ti o ba ti n se yii ni ode yoo koju si,ti ode yoo fi dana ibon ya eranko naa.Bi o tile je pe,opo igba,nibi ti o ti n se eleyii,ohun papaa maa n femi-in re kin-in.tori oju ki i  ri ina ori laipa ni ode e fi ohun paapaa a se,ti yoo si di eran ninu ikoko ode,nigbeyin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…