Home iroyin Kehinde Bamgbetan gbóríyìn fún àwọn agbófinró
iroyin - July 22, 2017

Kehinde Bamgbetan gbóríyìn fún àwọn agbófinró

Alaga Ijoba Ibile Ejigbo tele, Ogbeni Kehinde Bamgbetan, ti gboriyin fun awon oludibo, eleto idibo ati awon agbofinro lori ibo to waye ni Ipinle Eko lonii, paapaa ni adugbo Ejigbo.
Bamgbetan se amojuto ibo ni adugbo naa.
O so pe bi o tile je pe ojo koko di awon eniyan lowo, opo naa lo si pada tu jade.
O ni awon agbofinro se ise won bo se ye ki won o se e. Ko si ija, ko si ita.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…