APC borí ní Ìkòyí-Ọbáléndé
Egbe APC naa lo si n bori kaakiri ninu ibo Ijoba Ibile ti waye lonii o.
Esi to sese de ni Ikoyi-Obalende LCDA fihan pe oludije fun APC, Ogbeni Atanda Lawal, lo wole.
O ni ibo 7, 107, nigba ti eni to soju PDP ni 756.
Atanda ti so pe oun setan lati sise lati mu ileri oun se.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…