Home òpómúléró Ambode tò bí ọmọ sùkúù láti dìbò
òpómúléró - July 22, 2017

Ambode tò bí ọmọ sùkúù láti dìbò

 

Leyin opolopo odun ti Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode, ti kuro ni ile iwe alakobere, o tun se bi omo sukuu loni o.

O darapo mo awon to to gbooro lati dibo ni Ward A6, polling unit 010, Ogunmodede Junior College, Papa, ni Epe.

Niru asiko yii, opo gomina ati alase ijoba miiran maa n lo ipo won ni; won kii to. Sugbon Ambode to pelu awon eniyan to ku.

Latari eyi, opo eniyan lo n gboriyin fun un.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…