Ẹ funra o o
Orisiirisii ona ni awon eniyan n gba jale lode oni. Ilu ti buru de bii wi pe, mo tilekun ile ko so pe awon ohun ini wa labe aabo. E wo aworan isale yii ki a fi se arikogbon.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…