Home iroyin Bù jẹ, bù dànù Diezani: Ó ra ilé kan ní owó bíi bilionu mẹ́wàá náírà!
iroyin - July 20, 2017

Bù jẹ, bù dànù Diezani: Ó ra ilé kan ní owó bíi bilionu mẹ́wàá náírà!

Bi awon omo Naijiria ba pinnu lati sepe fun Minisita fun Oro Epo Robi tele, Diezani Madueke, afaimo ni ki epe naa ma mu u.

Idi ni pe awpon asiri bi o se ba owo ilu ninu je, to wa n han sode nayii, ni agbara pupo.

Ana ni a tun gbo pe ojo kan lo ko $35.7M sile fun ile kan to ra ni Babana Island ni Eko.

Owo naa ti bilionu mewaa naira ti a ba foo si owo tiwa. Olodumare o!

Ile ejo ti ni ki ijoba apapo o gbe ese le ile naa bayii.

Ohun ti ko tile wa yeni ni pe o se je pe bi ijoba Buhari se de ipo, ti Diezani aye rap ala jade ni Naijiria lo wa so pea run jejere (cancer) mu oun?

A ko si tii gbo ohun kankan nipa eyi lati nnkan bii odun meji seyin.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…