Qdot sọ ìdí tí òun kò fi lè tíì gbé orin tuntun jáde báyìí
Akorin apala igbalode, Qudus Oluwadamilare Fakoya, ti opo eniyan mo si Qdot Alagbe, ti so pe oun ko le tii ju orin miran sita bayii o.
O ni manija (manager) oun lo so pe ki oun ma tii ju tuntun kankan.
Nigba to n soro lori eto ori telifisan kan, Qdot ni un ni awon orin kan to gbayi pupo lowo, sugbon oun ko le tii gbe si afefe bayii.
Nigba ti won bi i leere boya o ni obinrin afesona, o ni oro afesona kankan ko tii si loju opon fun oun bayii.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…