Home ÀKỌ̀TUN Majek Fashek ṣe àtakò àwọn tó sọ pé ó ń mu cocaine
ÀKỌ̀TUN - July 19, 2017

Majek Fashek ṣe àtakò àwọn tó sọ pé ó ń mu cocaine

Akorin rege to ko SEND DOWN THE RAIN nigba kan, Majek Fashek, ti so pe lati ojo ti won ti bi oun, oun ko mu kokeeni ri.
O ni iro ni awon oniroyin to so pe oun maa n mu kokeeni n pa.
Sugbon sa o, ko soro lori boya oun n mu igbo tabi oogun oloro miiran.
Ninu iforowanilenuwo kan, Majek ni nigba ti oun lo si abe aabo ti won n pe ni rehabilitation, ko ye ki won oniroyin Naijiria gbe iroyin naa jade.
O ni ko si tunrtun ninu ki eniyan lo si abe aabo rehabilitation. Majek ni ni ilu oyinbo, ojoojumo ni awon olorin n lo rihaabu naa, ti awon oniroyin ko si so di asoosotan.
O ni ariwo ti won pa nipa aabo t’oun lo le fa ki awon ti won n oe oun sode ati awon eniyan miran to ku ma fe ba oun sise po mo.
O ni ni ilu oyinbo, orin oun SEND DOWN THE RAIN, ti oun se ni nnkan bii ogbon odun seyin, si n ta daadaa.
Majek ki awon oniroyin Naijiria maa gbe iru iroyin bee sita, dipo ki won ma ate ohun ti yoo se akoba fun oun jade.
Laipe yii, Majek Fashek yoo gbe awo orin tuntun jade.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…