Home LÁGBO ÀRÍYÁ Iyabo Ojo ṣe àfihàn ọkùnrin tó kọ́kọ́ fún-un láàyè láti kópa nínú fíìmù ní 1998
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 19, 2017

Iyabo Ojo ṣe àfihàn ọkùnrin tó kọ́kọ́ fún-un láàyè láti kópa nínú fíìmù ní 1998

Bi odo ba gbagbe orisun re, gbigbe lo maa n gbe.

Owe yii je ti gbajugbaja osere ti oruko re n je Iyabo Ojo.

Loju opo eniyan lojo Satide to lo, Iyabo foju eni to koko fun un laaye lati kopa ninu ere fiimu ni odun 1998.

Okunrin naa ni osere fiimu pataki ti o n je Keppy Ekpeyong Bassey.

Nibi aseye idije Africa Movie Academy Awards to waye ni Eko ni Iyabo ti so eyi, nigba ti won pe oun ati Ekpeyong jade sori itage, pe ki won gbe ife eye fun awon to bori.

Iyabo ni oun dupe lowo Ekpeyong to fun oun laaye lati se afihan ebun ti Olorun fun oun, to si je pe lati igba naa, oun ko ni idi kankan lati kabamo pe onifiimu ni oun.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…