Home LÁGBO ÀRÍYÁ Wọ́n ní kí n má fẹ́ Ademinokan, sùgbọ́n mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run – Stella Damasus
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 18, 2017

Wọ́n ní kí n má fẹ́ Ademinokan, sùgbọ́n mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run – Stella Damasus

 

Ewi ife to jinle ti Stella Damasus ati Daniel Ademinokan n ke fun ara won ti fee yi opo eniyan lori o.
Ti e ko ba gbagbe, Ademinokan ni baale Doris Simeon tele, ki oun ati Stella to fe ara won.
Bi Ademinokan se n yombo Stella pelu oro to dun bi ogede omimi, ni oun naa n korin ife to dun bi oyin ki i.
Awon mejeeji ni lati ojo ti won ti bi awon, awon ko ba eni to le fife han bi eni kookan awon ri.
Eyi lo mu ki Stella wa ranti igba to sese fe fe Ademonikan. O ni awon kan gba oun niyanju pe ko si anfaani ninu gbigbiyanju igbeyawo leeketa, pe ki oun jawo nibe.
Obinrin naa wa fi kun un pe oun gbe oro naa ko Olorun lorun, to ji je pe, ni bayii, oro naa ti ja si ope fun oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…