Remi Surutu fi ọ̀rọ̀ mọ Ọlọ́run lọ́kan, ó gbọnra nù lẹ́yìn ikú ọmọ rẹ̀
Leyin bii ose meji ti won sin oku omo osere fiimu ti a mo si Remi Oshodi Surutu, o jo pe o ti gba fun Olorun bayii o.
Obinrin naa sunkun sunkun, o si saaro omo naa ti oruko re n je Ayo, to si je pe arun aromoleegun – sickle cell – lo pa a .
Sugbon Surutu ti daraya. O si jo pe o ti fe pada si lokesan. O se afihan aworan fiimu kan ti won pe ni Gold Statue, nibi ti oun ati Gabriel Afolayan ti kopa.
O ni asiko niyi lati gbonra nu, ti oun si gba agbara tuntun lati owo Olorun.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…