Home iroyin   Kashamu Buruji lérí sí Gbenga Daniel lórí ìbò 2019
iroyin - July 18, 2017

  Kashamu Buruji lérí sí Gbenga Daniel lórí ìbò 2019

Apere pe koko le ma gbomi gbeyin ni 2019 ni Ipinle Ogun, lori idibo gomina, ti fara han bayii.
Meji ninu awon akoni oselu ipinle naa, paapaa ninu egbe PDP, Senito Buruji Kashamu ati Otunba Gbenga Daniel, ti bere sii ta’un sira won.
Ninu oro ti won so si ara won lori ero alatagba, ti ogbeni Wale Adedayo je ko di mimo f’araye lori Facebook, Kashamu ni gbogbo ete Daniel ni oun ti n ri. O ni gbogbo bi o se n ba orisiirisii awon to fe du ipo se ipade ni oun n ri. O wa so fun un pe ti Gbenga Daniel ba ro pe oun le gba isakoso PDP pada ni Ogun, o n tan ara re je ni.
Ninu esi tie, Daniel ko soro ibinu tabi ija. Ko so pe oun to maa ba oniwa ati eleyin se lori ibo naa. Sugbon o ni ko le daa ni oun n se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…