Home Orisirisi A ní láti ní sùúrù fún Buhari – Tinubu
Orisirisi - July 18, 2017

A ní láti ní sùúrù fún Buhari – Tinubu

Gomina Ipinle Eko tele, Asiwaju Bola Tinubu, ti ro awon omo Naijiria pe ki won se opolopo suuru lori ailera Aare Muhammadu Buhari.
Tinubu so ni ilu Kano nigba to lo ki gomina ipinle naa ku aseyinde Alhaji Maitama Sule pe niwon igba ti Buhari ti so fun ilu pe ara oun ko ya, ati pe oun ni lati wa iwosan lo oke okun, suuru lo ku ki a ni.
O ni otito ti Aare ni lati so loti so yen, tori gbogbo wa naa ni elran ara, to si je pe ara kii sokuta.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…