Home LÁGBO ÀRÍYÁ Iya Awero ko ba Yoruba loju je, o so oyinbo to dan moran ni AMAA
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 17, 2017

Iya Awero ko ba Yoruba loju je, o so oyinbo to dan moran ni AMAA

Agba osere, Lanre Hassan, ti opo eniyan mo si Iya Awero, fakoyo lale ojo Satide, nigba ti won pe e sori itage nibi ayeye African Movie Academy Awards ti won se ni Eko.
Won pe e gege bii okan lara awon to n gbe ebun fun awon to yege ni.
Iwonba oyinbo to so dan moran lenu re, ti oun re si tutu bi oun oba ilu oyinbo ti won n pe ni Queen.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…