Twitter ló dájà sílẹ̀ láarin èmi àti Wizkid – Skales
Okorin Hiphop ti gbogbo aye mo si Skales lo n ba awon oniroyin soro pe ki Olorun maa so wa ni pelu ero ayelujara Twitter ti o gbode kan. O ni ibe ni ohun ati awon kan ti n foro jomi-toro oro ti idahun ohun ti ta ba akegbe ohun Wizkid.
Skales ni gbogbo awon ololufe oun ati awon ore pelu ojulumo lo mo pe oun je eda to lojuti ti ko le ja, amo sadede ni oun dede ri ara oun ninu ija ori twitter. O si fi gbogbo nnkan bura sii pe gbogbo bi o se maa dara fun oun ati bi oun se maa se iranlowo fun awon alaini ni o maa n je oun lokan, ko ki n se ija rara.
O ni ibi ti oun de lonii, ko ki n se mimose oun, Olorun ni. O ni oun le ko orin, oun le jo, oun si le raapu ati bee bee lo.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…