Home iroyin Ọbasanjọ ló bẹ̀rẹ̀ ìgbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá – FUNAAB
iroyin - July 16, 2017

Ọbasanjọ ló bẹ̀rẹ̀ ìgbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá – FUNAAB

 

Ileewe FUNAAB, iyen Yunifasiti ti won ti n ko nipa ogbin ti sapejuwe Aare tele ni Naijiria, Oloye Olusegun Obasanjo gege bi eni to n ja fun iwa jegudujera.

 

Dokita Barr. Aboki Zhawa lo soro yi nigba to sabewo si Aare nile e to wa ni Hilltop Abeokuta nibi ti Obasanjo n gbe.

 

O ni Obasanjo lo koko bere ki won maa mu awon to huwa jegudujera pelu awon to da sile lakoko to wa ni ipo Aare, iyen ICPC ati EFCC to wa di nnkan tawon eeyan n beru bayii.

 

Baba Obasanjo lakoko to n soro so pe bo tile je pe ileewe naa koju opolopo isoro laipe yi, ti Adeda si ko won yo ninu iji lile to kolu won

O ni eko toun ri ko lara awon osise ijoba nigba toun je Aare ni pe won kii ko nnkan ti won ba fi lo. Bi awon kan ba mu imonran wa, awon kan ko ni so pe rara ko ri bee.

 

Leyin o reyin ni won so Obasanjo di pasito, to si gbadura fun won tori pe won ni adura e pelu nnkan to gbe awon wa kii nile ati wi pe won ni ileewe naa ko le nilosiwaju lai gbadura lenu alase tele naa.

 

Iroyin Owuro tun gbo pe awon alase naa tun lo sile Alake ile Egba, Oba Michael Adedotun Aremu Gbadebo lati lo kii fun bo se n gbaruku ti won ninu isoro ti won n doju ko.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…