Home LÁGBO ÀRÍYÁ   Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun abẹ́lé, Tonto Dikeh di oníwàásù
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 16, 2017

  Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun abẹ́lé, Tonto Dikeh di oníwàásù

O jo pe Olorun ti gbajoba ninu aye osere fiimu ti a mo si Tonto Dikeh. Ni bayii, oro Olorun, oro bii iwaasu ko jinna si enu re mo.
Lenu ojo meta yii, osere fiimu naa, ti o tun maa n korin leekookan, ri l laasigbo ninu igbeyawo re pelu Ogbeni Olakunle Churchill, eni ti won pe ni omo-omo Oloye Olusegun Obasanjo.
Igbeyawo naa fo yangayanga ti won ko ri i sa, debi pe awon obi arabinrin naa ti da owo ori ti won gba lowo idile Churchil pada.
Tonto Dikeh ni oun ti di atunbi ninu Oluwa.
Sugbon sa o, o se alaye pe born again t’oun ko ni ki oun ma wo aso asiko.
Gbogbo bob a se n lo, IROYIN OWURO yoo maa ro o.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…