Home ÀṢÀ ÀTI ÌṢE Ìlù, orísun ìdùnnú
ÀṢÀ ÀTI ÌṢE - July 16, 2017

Ìlù, orísun ìdùnnú

Ilu je ohun elo idaraya,ti a  n lo lopo igba,lati safihan bi idunu eniyan se po to.ldi niyi ti Yooba ti maa n so pe,sekere ki i bawon rode ibanuje.Ni bi ti idunu atayo ba fikale si,ni ilu maa n wa.Oniruuru ilu ni o wa ni ile yooba ti o je ilu ibile. Ona meji taara ni a le pin a won ilu si,akoko ni ilu ti o je mo ayeye amuluudun gbogbo,bi i ,igbeyawo,ikomojade,ifinijoye,sile,iwuye,isinku agba ati bee lo.

Orisii ilu yii ni dundun.llu dundun ni awon eya bi i, iya ilu,atele iya ilu,kerikeri,isaaju,omele ako,omele abo, gangan ati gudugudu,koda, awon kan gba pe gudugudu saaju dundun dele aye,nitori naa ni a se n powe pe, gudugudu kii sojugba dundun.Ko sibi ariya ti a ko ti le e ba dundun pade, nigba mi- in a maa n da sekere ati aro po mo dundun,be e ilu dundun ti ko ni sekere ati aro, ni a n pe ni “Wata”. Ojulowo omo yooba, iwe iroyin tiyin re e,ti o n so nipa asa tiwa, e gbaruku ti i, e gbe e laruge, eeyan to so ile nu,onitoun lo so apo iya ko.Oro nipa ilu n tesiwaju ,ire o.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…