Home ÀRÒJINLẸ̀ Ìlú ńlá ló ń jẹ́ Nàìjíríà
ÀRÒJINLẸ̀ - July 16, 2017

Ìlú ńlá ló ń jẹ́ Nàìjíríà

Ibi ori dani si laa gbe. Loooto ni pe gbogbo ohun ti Olorun ko fe ni aseju, se bii awon to n doju le awon onijibiti wa ni? Awon kan ma ti n so pe aseju Buhari ti po ju. Won ni awa omo Naijiria ko ran an to bee. Ni okan ti eyin alarojinle, se efe ni eleyii ni abi awada?

Awon kan ni gbogbo oso ati aje ilu ni awon onijibiti ti be lowe si Buhari, won ni aisan re o ki n se oju lasan, bi o tile je pe Aisha Buhari gan an n funra si awon olote kan. O n salaye fun awon omo Naijiria pe oko oun ko ni pe de, lati wa doju ti awo eranko ati olote orileede yii.

Awon alarojinle kan ti wu ina ote lori ete buruku awon ota to n se bi ore ninu isejoba naa. Awon onijibiti kan ti da owo ti won ko pada nigba ti awon kan taku wonnle pe iku nikan lo le gba owo naa pada lowo awon. Eledua lo maa saanu wa ni ilu yi, oro gbogbo kii se lori alabahun ni oro awon alagbara kan ni ilu yii. Ko si jibiti kankan ni ile yii ati ni oke okun ti owo won ko fere si nibe. Bawo ni iru awon alagbara yii se fe ki ilu toro. Gbogbo awon to n je labe won naa ni won n lu ilu “boledogun, ko dogun, boledote ko dote”. Oro wa dowo Eledua ni ilu yii..

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…