Home iroyin Ambode lé Baale Shangisa kúrò lórí oyè pátápátá
iroyin - July 16, 2017

Ambode lé Baale Shangisa kúrò lórí oyè pátápátá

Ajaga to wa lorun Baale Shangisa Magodo ni Ipinle Eko, Oloye Yusuf Ogundare, ti wa po si bayii o.
Gomina ipinle naa, Ogbeni Akinwunmi Ambode, ti gba ileke lorun re, to si le e kuro lori oye patapata.
Ese Ogundare ni pe won ni o ji ara re gbe pamo, o wa paro fun araye pe won ajinigbe lo gbe oun lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…