YEMI MY LOVER: Osinbajo kéwì ìfẹ́ fún ìyàwó rẹ
Ta lo ranti fiimu Yemi my Lover? Adele Aare Olori Orile-ede yii, Ojogbon Yemi Osinbajo, ti ran opo eniyan to ba ti gbagbe fiimu naa leti o.
Osinbajo se eyi nigba ti o k’ewi ife fun iyawo re, Iyaafin Dolapo Osinbajo, eni ti o pe aadota odun lojo Satide.
Osinbajo ni, “Iwo ni ebun pataki fun mi lati owo Olorun. O n daabo bo mi. Iwo ni oluranwo legbee mi, iye (wings) to daabo bo mi.”
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…