Home iroyin Kí ìyàwó Akeredolu má sàfira, ọmọge kan ń kú fún gómìnà lórí Twitter
iroyin - July 15, 2017

Kí ìyàwó Akeredolu má sàfira, ọmọge kan ń kú fún gómìnà lórí Twitter

Ki iyawo Akeredolu ma safira, omoge kan n ku fun gomina lori Twitter
To ba je pe ohun ti a ba fi sile ni ewure maa n gbe loooto, Iyaafin Betty to je iyawo Gomina Ipinle Ondo, Rotimi Akeredolu, ko gbodo safira rara.
Idi oro ni pe olomobinrin pupa roboto kan, to dara bi egbera ti n fi ife han si gomina naa.
Obinrin naa ti o pe oruko ara re ni Faya so pe irufe awon okunrin to wu oun bayii ni awon agbalagba ti won rewa daadaa, ti won sit un ri jaje, yato fun pako.
Ni pataki, o daruko Gomina Akeredolu, to si so pe oun n wa a bi eni wa owo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…