Home LÁGBO ÀRÍYÁ Genevieve ń pa Emmanuel Adebayor bí ọtí
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 15, 2017

Genevieve ń pa Emmanuel Adebayor bí ọtí


Agbaboolu Togo ati Tottenam tele, Emmanuel Adebayor, ko gba boolu kan dabi alara lowolowo yii, sugbon nnkan kan wa lokan re to fe gba.
Koda, ohun to fe gba ju boolu lo.
Omo Naijiria ni tele ko to di omo Togo, to si je pe Ejigbo, ni Ipinle Osun, ni orirun re.
Bi ko tie je omo Naijiria mo, o fe ba Naijiria tan. O ti ri ododo kan ni agbala Naijiria to fe ja. Gbajugbaja osere fiimu, Genevieve Nnaji, si ni ododo naa.
Foto arabinrin yii kan ni Adebayor ri ni o ri ori re fi fe daru patapata.
O ki Genevieve tokantokan. O si kira fun un gidigidi.

Nigba ti Adebayor yoo ba a je, o ni ki Genevieve jowo pe oun lori foonu oun.

IROYIN OWURO war o pe okunrin lo koko maa n pe obinrin bi oro ba ri bayii.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…