Home LÁGBO ÀRÍYÁ Femi Adebayo rọ̀jò àdúrà lé àkọ́bí rẹ̀ lórí
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 15, 2017

Femi Adebayo rọ̀jò àdúrà lé àkọ́bí rẹ̀ lórí

 

Osere fiimu, Femi Adebayo, ro ojo adura leri akobi omo re, Firdaos, lojo Satide, nigba ti o se ojo ibi.

Femi gba adura ki Olorun tubo maa bukun igbesi aye omo naa. Ni pataki, gege bi opo obi se maa n fe, o ni ki Olorun gbe omo naa ga ju egbe re lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…