Àbúrò Fashola la ewu iná ńlá kọjá
Olorun oba nikan ni ko je ki Minisita fun Oro Akanse Ise, Agbara ati Ilegbee, Ogbeni Babatunde Fashola, sun ekun lori aburo re kan, Ibrahim Ademola Fashola, lodun to lo si odun yii.
Olorun nikan, ati awon dokita, lo yo Ibrahim kuro ninu ewu ina nla to jo ile re guagua.
Ina naa jo oun naa, sugbon Oba Oke ti gbakoso.
Idi niyi ti oun naa se n dupe aanu Olorun to yo o.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…