Home iroyin Love in Tokyo: Pastor Adeboye pe iyawo re ni ‘My Baby’
iroyin - July 13, 2017

Love in Tokyo: Pastor Adeboye pe iyawo re ni ‘My Baby’

 

Bi eniyan ba n wo Oludari Agba Lagabaye fun ijo Redeemed Christian Church of God, Pastor E. A. Adeboye, to ba gori pepe to n waasu, oluware ko ni mo pe baba naa mo ere ife kusimilaya a se. Sugbon sa o, Daddy G. O. ti fihan pe oun naa ni ede ife to jinle lenu.
O fi eyi han nigba ti o n ki iyawo re, Pastor Foluke Adeboye, ku oriire ti ojo ibi odun kokandinlaadota re (69 years) lojo Alamisi.
Dipo ti yoo fi pe e ni iyaafin tabi mama, Baba Adeboye pe iyawo re ni ‘Baby’, gege bi awon omo ode oni se maa n pe ololufe won lede oyinbo.
Baba Adeboye so lori ero alagbeka Instagram re pe, “Happy birthday to my baby’.
Ki Olorun tubo je ki won pe fun ara won o.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…