Kò sí ìjà láàrin ẹ̀ka ìjọba kankan – Lai Mohammed
Alhaji Lai Mohammed to je Minisita fun eto iroyin ati asa ni orileede yii ni Olorun ko ni fun awon to fe maa si ijoba lona se. O ni, ko si ija laarin adele Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo ati Aare Buhari, Ko si ija laarin awon Seneto ati adele Aare pelu awon eka ijoba to ku gbogbo, o ni ohun to fere da bi aigbo-ara-eni ye ni awon ti yanju ni itubi-inubi.
Minisita tun gba awon oniroyin niyanju lati maa ri awon ohun to dara ijoba ju aidara lo. O ni riri eyi to dara lo le ran gbogbo wa lowo. Eyi ni ko ni je ki awon omo Naijiria maa ni irewesi nipa ilu ti ori da wa si.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…