Home Orisirisi Ìdùnnú subú layọ̀ f’Ádélékè
Orisirisi - July 13, 2017

Ìdùnnú subú layọ̀ f’Ádélékè

Yoruba bo, “won ni inu eni kii dun ki a paa mora”. Eyi lo difa fun Ogbeni Ademola Adeleke, Seneto ti won sese dibo yan ni ipinle Osun. Bi o se gbo wi pe oun jawe olubori lo ba fi ijo sii. Orisiirisii ijo ni Senato yii n jo kiri sugbon eyi to see fihan niyi ninu re….

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…