Yegede fun PDP! Makarfi da Sheriff mole ni Supreme Court
Ojo nla, ojo idunnu ni oni je fun egbe Peoples Democratic Party o.
Idi nip e ija ajaatuka to ti n sele ninu egbe naa lojo to pe ti fe dopin.
Ile ejo giga Supreme Court ni Abuja ti da alajaagbila Ali Modu Sheriff lebi, won ni ko leto si ipo alaga egbe, ati pe Ahmed Makarfi ni kinni naa to si.
Pelu isele yii, iberu to ti n sele lori pe kin ni yoo sele si PDP ti won ba da Sheriff lare ko waye mo.
Egbe naa ni anfaani lati tun ile ara re to, ko sig be ija koju APC ninu awon ibo to n bo.
IROYIN OWURO ranti pe ose to lo naa ni PDP da APC mole ni Ipinle Osun, ninu idibo si ile igbimo asofin Senate, nibi ti Ademola Adeleke ti jawe olubori.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…