Home iroyin Saraki àti Ekeremadu ní ìjọba ìpínlẹ̀ Kogi dójú lé Melaye
iroyin - July 12, 2017

Saraki àti Ekeremadu ní ìjọba ìpínlẹ̀ Kogi dójú lé Melaye

Nibi ijokoo ojo Isegun  ni olori ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki ti ni oro Kogi lowo kan abosi ninu. O ni ko si owo ni ilu to ki gomina ipinle maa nawo bii milionu mewaa lori ipolongo ibo lati le Dino Melaye kuro ni Abuja.

Saraki ni oun kuku ti se gomina ri ni o je ki oun mo ibi ti bata ti n maa n ta awon gomina lese.

Ekeremadu to je igbakeji re naa kin in leyin pe olori idajo ipinle kogi gan an ko ko ibi ara si iwe ofin ile yii. O ni, o ye ki o maa kaa daadaa ki o to maa soro, ki o le baa mo ohun ti o ba ofin mu ati eyi ti ko ba ofin mu ko to maa doju ti ara re.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…