Home LÁGBO ÀRÍYÁ “Don Moen” Kò kú, ó wà láàyè
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 12, 2017

“Don Moen” Kò kú, ó wà láàyè

Don Moen ko ku o. Iroyin kan ti n ja ranin-ranin lati bii wakati merin si marun-un bayii nipa iku Don Moen. Won ni aisan inu rirun lo paa si ile-iwosan General Acute Care (GAC) to wa ni iku Califonia.

Okan ninu awon ebi re to ba awon oniroyin soro ni ko si ohun to joo rara. Won ni saka ni ara da, koda aisan inu rirun re ko daa laamu mo.

Ninu ero ayelujara-won re ti gbogbo aye mo si twitter ni o ti se afihan foto “iran merin ti kii tosi” ninu ebi re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…