Home iroyin ÌDÁJỌ́ PDP: Jonathan sọ̀rọ̀ ìdùnnú,  Olùbádámọ̀ràn Fayose kó otí beer síta
iroyin - July 12, 2017

ÌDÁJỌ́ PDP: Jonathan sọ̀rọ̀ ìdùnnú,  Olùbádámọ̀ràn Fayose kó otí beer síta

Aare ana, Dokita Goodluck Jonathan, pelu ogooro omo egbe PDP ti won n dawoo idunnu lori bi ile ejo to ga julo, Supreme Court, se pa Modu Sheriff lenu mo, lori ta ni alaga egbe naa.

Ni owuro oni, awon adajo agba naa ni Ahmed Makarfi ni alaga, ki Sheriff lo wa ibi kan fidi le.

Ninu oro re, Jonathan kan saara si awon adajo naa. O ni idajo han fihan pe adajo ododo sit un wa lorile ede.

Ni Ipinle Ekiti, ayo ati idunnu joba lokan awon omo egbe PDP ni.

Koda, awon kan ko bia (beer) ati waini jade, ti won fi n we kinni ohun.

Lara won ni Olubadamoran fun Gomina Ayo Fayose lori oro Iroyin, Ogbeni Lere Olayinka, ati okan lara awon alaga ibile ni ipinle naa, Alagba Olanrewaju Omolase, ti a ri won nibi ti won ti ko oti sile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…