Home iroyin Èmi kò bẹ́ni kankan jà o – Fasola
iroyin - July 12, 2017

Èmi kò bẹ́ni kankan jà o – Fasola

Minisita fun ina mona-mona, ona ati ise ni Naijiria, Babatunde Fasola lo salaye yii ni igba to n ba awon oniroyin soro ni opin ipade to se pelu awon olokoowo. O ni oun ko ba ile igbimo asofin kankan ja.

Oun kan n salaye bi o se ye ki nnkan ri fun won ni. O ni ki oun ma tile je minisita rara, sebi omo Naijiria ni oun naa to si leto lati so ero oun sita nipa bi nnkan se ri. Fasola ni gbogbo akitiyan bi ilu se maa dara ni o je oun logun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…