Damola Adetunji ké gbàjarè lórí àwọn tó ń fi orúkọ rẹ̀ lu jìbìtì
Osere fiimu pataki, Damola Adetunji, ti ke gbajare lori awon 419 kan ti won n fi oruko re gba owo kiri lowo awon eniyan.
O se e ni alaye pe oun ko ran enikeni nise lati toro owo lowo eni kankan.
Gege bi o ti so, o jo pe awon omo Yahoo-Yahoo kan lo n lo awon aka-n-ti re lori ero ayelujarawon, gege bii Facebook, lati lu awon ara ilu ni jibiti.
O wa se ikilo pe enikeni ko gbodo da awon to ba wa ba won loruko oun lohun rara.
Bi a ba ranti, awon onijibiti ti lo oruko opo gbajugbaja lati se ise laabi bayii.
Lara awon eniyan ti won ti fi oruko won lu jibiti ni Pastor E.A . Adeboye ati iyawo re, Baba Latin ati Sanyeri.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…