Home ÀKỌ̀TUN Zahra, Olumba Olumba mú ìròyìn ayọ̀ wá lórí Buhari
ÀKỌ̀TUN - July 11, 2017

Zahra, Olumba Olumba mú ìròyìn ayọ̀ wá lórí Buhari

Ailera Aare Muhammadu Buhari ti ko opo eniyan lokan s’oke, paapaa awon ololufe re kaakiri Naijiria.
Orisiirisii nnkan ni a n gbo.
Eni to mo otito nipa ibi ti itoju Aare de n so o; elomiran ti ko mo naa n so ohun to wu u.
Sibesibe, adura ni opo eniyan n se pe ki Buhari de layo ko wa pari ise ti Naijiria gbe le e laya.
Sugbon ireti mran tun ti je jade, latari bi okan lara omo bibi inu Aare, iyen Zahra, se so pe ara baba oun ti n ya.
Koda, obinrin naa, to se igbeyawo laipe yii, so pe laipe, Buhari yoo fie se ara re tele ni Naijiria.
Bakan naa, Olori awon ijo Brotherhood of the Cross and Star, Alagba Olumba Olumba Obu, ti so asotele pe Buhari yoo pada laipe pelu ayo ati alaafia.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…