Torí Jaiye Kuti, Pasuma kọjá sí London
Lai fota pe, idan si n lo lagbo fuji o. Awon eniyan to wa nidi ikoko obe orin naa ko kuro nibe, tori won ko fe ko jona.
Okan pataki lara won ni Oga Nla Fuji, Wasiu Alabi Pasuma.
IROYIN OWURO gbo pe Pasuma koja lo si ilu London bayii, nibi ti o ti n sere fun onifiimu ti a mo si Jaiye Kuti, lojo Jimoo.
Nigba to ba de, Pasuma ni ere pataki kan ni ilu Eko lopin ose yii.
IROYIN OWURO tun gbo pe ki osu yii to pari, Paso yoo wo studio lati se awo orin tuntun.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…