Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Ọ̀rọ̀ kan àgbààgbà: Osinbajo lọ ṣe àbẹ̀wò sí Buhari ní London
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - July 11, 2017

Ọ̀rọ̀ kan àgbààgbà: Osinbajo lọ ṣe àbẹ̀wò sí Buhari ní London

 

Adele Aare Orile-ede yii, Ojogbon Yemi Osinbajo, ti lo se abewo si oga re, Aare Muhammadu Buhari bayii.

Oni naa ni Osinbajo gbera pa, tori o jo pe okan re n fa Buhari.

Olubadamoran Iroyin for Osinbajo, Ogbeni Laolu Akande, lo so eyi di mimo.

Eyi mu ni ranti orisii ere boolu kan ti awon omode maa n gba nijoun.

Ninu ere naa, ko ni si golikipa kankan lenu awon. Won a wa so pe ‘A fi Olorun sole’.

Sugbon sa o, Akande ni ni kete ti Osinbajo ba ti se abewo tan si Buhari ni yoo maa bo nile.

Adura opo eniyan ni pe ki Osinbajo mu iroyin ay obo, ki ara Aare o si ya layo, ki oun naa le pada si Naijiria lati maa ba ise re lo.

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…