Oriléèdè Germany ń dúró de Ààfáà Muideen
Gbajugbaja oniwaasi ati atona Musulumi, Aafaa Muideen Bello, si n tesiwaju lori itankale esin Islam o.
Lati opolopo odun seyin ni Aafa Bello ti n sise Olorun, to n se waasi itagbangba, awo orin ati fideo ti won n gbe sita.
Bi o se n se kaakiri Naijiria naa lo n se loke okun.
Lowolowo yii, Aafaa Muideen n mura lati lo si Germany, nibi ti yoo ti lo se waasi fun awon Mumini.
Ogooro awon elesin Islam lo n duro de e nibe.
IROYIN OWURO gbo pe orile-ede ti baba naa ko tii bewo fun waasi ko wopo lagbaaye.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…