Idi ti Liz Anjorin se bu sekun nigba to n gbe fiimu re tuntun jade
Ojo pataki ni Jimoo to koja je fun osere fiimu ti a mo si Liz Anjorin o.
Ni ilu Eko, o ko fiimu re tuntun jade bi omo ojo mejo.
Fiimu naa ni o pe akole re ni OWO NAIRA BET.
Sugbon aseye naa mu omi jade loju re.
Idi ni pe nigba to gun ori itage lati dupe lowo awon eniyan to wa, ero Olorun ba a nip ape ero po bi omi, ti awon eniyan jankan-jankan ko gbeyin.
Lara won ni Alaafin ti Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, iyawo Minisita fun Oro Akanse Ise, Agbara ati Ilegbee, Iyafin Abimbola Fashola; ati onisowo moto pataki, Alhaji Lanre Shittu.
Bi Liz se so pe ki oun soro bayii, omi lo n da sile loju re peerepe.
Eyin-o-reyin lo to so lori ero alatagba Instagram bi inu oun se dun to, to si dupe gidi lowo awon to ye e si.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…