Home ERÉ ÌDÁRAYÁ IKÚMÚYÌÍWÁ: Adémọ́lá Adélékè di Sẹ́nítọ l’Ọ́ṣun
ERÉ ÌDÁRAYÁ - July 9, 2017

IKÚMÚYÌÍWÁ: Adémọ́lá Adélékè di Sẹ́nítọ l’Ọ́ṣun

Eyi to wu ka wi, ti Olorun lase. Ninu eto isejoba Democracy naa, ti awon oludibo lase.
Eyi je eko kan pataki ti teru-tomo ti n ko latai bi aburo oloogbe Isiaka Adeleke, iyen Ademola Adeleke, se di Senito bayii, nipa bibori ninu ibo ti won di ni Ipinle Osun ni ojo Satide.
Gomina Rauf Aregbesola ati egbe APC ja raburabu, sugbon awon oludibo ni Ademola Adeleke ni awon fe.
Ko si eni to mo Ademola Adeleke tele, sugbon iku to ba ola je ni idile won naa lo mu adun aseyori naa fun. Eyi lo mu ki awon eniyan kan so pe boya Senito Ikumuyiwa ni a ba maa pe e.
O jo pe awon oludibo boju aanu wo idile naa, latari kiku ti Isiaka Serubawon ku, ti egbe APC sit un ko lati fa aburo re kale.
IKUMUYIWA: Ademola Adeleke di Senito l’Osun

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…