Home Orisirisi Fúnkẹ́ Akíndélé, Ini Edo: Ẹ kú àlejò omíyalé ní Lekki
Orisirisi - July 9, 2017

Fúnkẹ́ Akíndélé, Ini Edo: Ẹ kú àlejò omíyalé ní Lekki

  Aja oyinbo sunwon, sugbon o ku atiperan fun ni je. Bee, a kii dara ki a ma ni abuku kankan. Gege bee ni adugbo kan ti opo eniyan fe maa n gbe ni ilu Eko. Ibe naa ni Lekki, nibi tiile alarabara po si, ti eniyan si ti n ki aje kuukale. Gege bi awon olowo yoku, opo osere to ri jaje yato si pako lo nile si Lekki. Lara won ni Funke Akindele, Davido ati Ini Edo. Sugbon wahala nla kan to wa ni adugbo naa ni ti omiyale, agbara ya soobu to maa n be awon eniyan Lekki wo leekookan. Leyin pe owo nla ni won fi maa n fi yeepe le omi salo ti won ba fe kole nibe, bi ojo ba de naa, o maa n da won si iyonu lopo igba. Eyi lo n sele lowolowo bayii, tori omi nla ti gbajoba ni awon ona ati ile kan, to je pe inu fuu aya fuu ni awon onile naa wa. Eyi fa a ti awon tyo n gbe ni ori ile gberefu ni mainland, ti awon ara Lekki maa n fii se yeye tele pe talika ni won, ki awon naa maa ki awon ara Lekki naa pe won ku alejo omiyale o. Paapaa, awon alatileyin awon osere wa naa, ti a n pe ni fans, n kan si awon alariya yii pe won ku alejo omi lotun-un losi. Adura tiwa ni pe ki olweri tete je ebure, ebure awo olugbebe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…