Home iroyin Egunje koba olopaa merin, won ti le won danu
iroyin - July 9, 2017

Egunje koba olopaa merin, won ti le won danu

 

Okanjua ati ijekuje ti se akoba fun olopaa merin kan bayii o.

Oga olopaa ni Naijiria ti le awon merreerin danu, latari bi won se fipa gba egberun lona aadota naira (N50,000) lowo arakunrin kan ni Ijebu Ode.

Okunin naa lo ko leta ehonu si oga olopaa, nibi to ti se alaye ohun ti oju re ri.

O ni oun lo ba oga oun kan gba owo ni banki, ni awon olopaa mereerin ba pade oun lona.

O ni nigba ti won da oun duro, won gba foonu oun, won si gbe oun lo si ago won ni Ijebu Ode.

O ji won so pe oun n se Yahoo-Yahoo, oun si so pe ko ri bee.

Loro kan sa, gege bi okunrin naa ti so, o ni awon olopaa naa gba owo naa lowo oun ki won to fi oun sile.

Ibinu oro naa lo fa a ti won fi le awon olopaa naa danu.

Awon eni oro kan ni Mufutau Olaosun, Adebayo Temitope, Bakare Taiwo, a corporal ati Adesoye Ayokunlehin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…