Eemo wolu! Ole ji foonu Ooni Oba Ogunwusi ni Abeokuta
O seese ki awon orisa ile Yoruba maa binu bayii o, latari iwosi nla ti a gbo pe won fi lo Ooni Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, lojo Satide to lo.
Nibi igbeyawo omo Gomina Ipinle Ogun, Senito Ibikunle Amosun, ati Iyaafin Abike Dabiri-Erewa, ni a gbo pe awon karanbaani eniyan naa ti ji foonu Kabiyesi gbe, to si je pe gbogbo akitiyan ti won se ki won le ri i lo ja si pabo.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…