Home LÁGBO ÀRÍYÁ Adémọ́lá Adélékè: Orin wo ni Davido yóò kọ lórí àseyọrí àbúrò bàbá rẹ̀?
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - July 9, 2017

Adémọ́lá Adélékè: Orin wo ni Davido yóò kọ lórí àseyọrí àbúrò bàbá rẹ̀?

Nigba ti Senito Isiaka Adeleke Serubawon je Olorun nipe lairoti ni ose die seyin, lara awon eniyan to baraje ni akorin hip hop Davido.
O faraya debi pe o pa awon owe kan to jo pea won kan lo n ba wi.
Idi ni pe egbon baba re (Baba Olowo) ni Serubawon je.
Bayii ti aburo Baba re Ademola Adeleke ti wa bori ibo Senito ni Osun, orin wo ni Davido yoo ko bayii?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…